Search Options

Results per page
Sort
Preferred Languages
Advance

Results 1 - 1 of 1 for ebbe (0.01 sec)

  1. docs/yo/docs/index.md

    ### Àtúnyẹ̀wò
    
    Ni akopọ, ìwọ yóò kéde ni **kete** àwọn iru èròjà/pàrámítà, kókó èsì API, abbl (i.e. àti bẹbẹ lọ), bi àwọn èròjà iṣẹ.
    
    O ṣe ìyẹn pẹ̀lú irúfẹ́ àmì ìtọ́kasí ìgbàlódé Python.
    
    O ò nílò láti kọ́ síńtáàsì tuntun, ìlànà tàbí ọ̀wọ́ kíláàsì kan pàtó, abbl (i.e. àti bẹbẹ lọ).
    
    Ìtọ́kasí **Python**
    
    Fún àpẹẹrẹ, fún `int`:
    
    ```Python
    item_id: int
    ```
    
    Registered: Sun Sep 07 07:19:17 UTC 2025
    - Last Modified: Sun Aug 31 10:49:48 UTC 2025
    - 24.1K bytes
    - Viewed (0)
Back to top